Oh death...where is thy sting?...The news of sudden/ untimely demise hit me like a big bullet
My dearest. Debla as I used to call you & u call me. An' Toyin..... My dearest Àbúrò,paddy,goon,gist partner....So d journey of 63 good years of having u as my Ẹ̀bínẹ́yìn has now come to an end? No, because you are n will forever be in my heart.
You were such a lively exhuberant,bobbling, handsome,pimples-free-face, with dimpled chubby cheeks, encouraging smiles,loving, caring,auscidious,bold,brilliant,gentle, easy-going, resilient,dutiful, responsible vibrant,quintessential pleasant in all ramifications of life. When we were both on video chat on February 25th and March 1st...you didn't appear sick....O ye Ọlọrun.
Debla, am missing and will miss you forever as a week never went by without video chatting or talking...but my consolation is that when we meet again on Resurrection Day...we shall continue from where we stopped.
Continue with your well deserved eternal RIPP in the Bosom of your Creator/Redeemer.
Sun Re o....
Ọmọ Olowu Oduru,Ọmọ a jí f'epé ṣere.
Ọmọ Oriwu l'Agbowa Ikosi
Ọmọ Ikosi mọ idẹ.Ọmọ a ṣ'ale gẹgẹ bí ẹní ko r'obirin ri.Bẹẹ ìgbà Obirin mbẹ nínú Àgbàlá
Ọmọ L'Aiye Ode L'Afoṣẹ, ti kii f'afọ̀ danu. Ọmọ Itunkanna ti nf'asẹ mu ọti. Ọmọ a jí mu'da.Omo Elenpe l'Ode-Remo. Ọmọ Lodo meri,Ara Ẹpoṣo. Ọmọ a jí f'asẹ mu ọti. Ọmọ Oba ti ngb'ade l'Oba l'ori. Ọmọ Apondelẹ bí Oburo. Ọmọ o ni nkan t'oyibo ko ni n'le. Ọmọ alabẹ́reẹ́ meta...ekinni kan, ekeji tẹ̀, ẹkẹta lo fi ran igba aṣọ. Ọmọ Oloríta marun, ẹkẹfa n'ibusi. Ọmọ Oba Akara kúta, k'ọmọ ẹlẹkọ ma polowo mọ.Omo Olobi woroko ẹ̀ba ona..eyi t'o bá dara..a wo s'agbon ẹní jẹ.. eyi ti ko dara... ẹiyẹ burúkú níí fi je. Ọmọ elewu woyi-woyi..b'o ti nwọ funfun..l'o nwọ pupa. Ọmọ a ke n'igbo,k'ẹru b'ara ọna. Ọmọ a de 'le teji-teji. Ọmọ Ṣakeeke l'ọna ẹri(odò) Ọmọ mẹ mu.. mẹ mú, ma fu vhinnnnn.
Sleep on my dearest Àbúrò. Your Sister...Toyin Oworu
